Ẹkáàbọ̀ sí Bitkoini, ẹ̀yin tí ẹ n bẹ̀wá wò!

Láti ọwọ́ Jameson Lopp 2017/11/19open in new window

Àwọn wọ̀n yín ni ohun tí ẹ ma n bèèrè jùlọ(FAQ):

Ìbéèrè: Ìbéèrè: Tani kín fi ọkàn tán?
Èsì: Kò sẹ́nìkan.

Ìbéèrè: Nígbàwo ni ó yẹ kí n tàá?
Èsì: Kí a má ri.

Ìbéèrè: Ṣé Bitkoini ń kú nítorí ______?
Èsì: Rárá.

Ìbéèrè: Irú ètò wo ni mo ti ara mi bọ̀?
Èsì: Kò sí ẹni tí ó mọ̀.

Ìbéèrè: Báwo ni mo ṣe lè kọ́ nípa rẹ̀ si?
Èsì: A ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn àkóónú. Tàbí kí o lọ sí lopp.netopen in new window

Awọn onitumọ
Oladele Falese

Olufowosi
BitMEX